Jump to content

Wq/yo/Ojúewé Àkọ́kọ́

From Wikimedia Incubator
< Wq | yo
Wq > yo > Ojúewé Àkọ́kọ́
Yoruba wikiquote


Image
Yoruba Wikiquote
Wikiquote jẹ́ iṣẹ́ akanṣe Wikimedia tí ó jẹ́ ọ̀fẹ́, tí ó sì wà ní ọ̀pọ̀ èdè. Ó ń kó àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn olókìkí sọ, àwọn ọ̀rọ̀ inú ìwé, ọ̀rọ̀ àsọyé, fíìmù, òwe, àti àwọn ọ̀rọ̀ pàtàkì mìíràn jọ, ó sì ń ṣètò wọn kí ó lè rọrùn fún àwọn ènìyàn láti rí àti láti lò.

Fún èdè abínibí, Wikiquote lè ṣe pàtàkì gan an fún òwe, àṣà ọ̀rọ̀, àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ ọgbọ́n, àti àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn olókìkí sọ, kí wọ́n má bà a sọnù. Ó tún lè jẹ́ kí àwọn ohun èlò wọ̀nyí wà lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì, kí ó sì mú kí èdè náà ní ìfarahàn àti ipa tó pọ̀ sí i ní àgbáyé ẹ̀rọ.