Image

Wo ohun tuntun pẹ̀lú àwọn block

Ẹ̀dà pàtàkì tuntun ti WordPress ní àwọn àtúnṣe tó lè mú kí àwọn block tó ò ń lò sunwọ̀n sí i, kó sì mú kí ìrírí kíkọ́ ìkànnì rẹ dára sí i. Gba àlàyé kíkún nípa ohun tó wà nínú ẹ̀dà tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde.

Image